jba (Live)-文本歌词

jba (Live)-文本歌词

K1 De Ultimate
发行日期:

Àyìndé ti gb’órin ẹ̀ dé o o o Mo gba ara tì ẹ SEGO Mo kí Ayédáadé Àyìndé National President Ẹ máa jẹun lọ Lát’ara Musitapha mi SEGO (Musitapha) Mo k’Áyìndé mi Musiliu (Ayédáadé) Gbogbo yín pátá pátá T’ẹ́ ẹ jẹ́ ọmọ fún Aṣíwájú Àkànbí olódó idẹ President kó o pẹ́ Ìjọba gbogbo lọ́wọ́ wa ló wà (Adé orí ọ̀kín) Ìjọba gbogbo lọ́wọ́ wa ló wà (Adé orí ọ̀kín) Gbogbo woro sí woro Gbogbo wòrò sí kọ̀rọ̀ Ọlọ́hun ló ní ó rí bẹ́ẹ̀ Bó bá ṣe ọmọ èèyàn kan ni Wọ́n á ti ṣẹ́’gi ọlà yìí dáná Ìjọba lọ́wọ́ wa ló wà (Adé orí ọ̀kín) Gbogbo yín ẹ kú ọ (Gbogbo yín ẹ kú ọdún) Gbogbo yín ẹ kú ọ (Gbogbo yín ẹ kú ọdún) Mo ti kí ẹ Àdufẹ́ Mo gba ara tì ẹ mo fi kí àwọn tó kù Mo kí Dámilọ́lá Òní Movie ẹ tuntun t’ó o ṣe yẹn Á máa tà á gbówó wa’lé Fúnkẹ́ Akíndélé, Fẹ́mi Adébáyọ̀ gbogbo yín pátápátá Ẹ máa jẹun lọ, Ìyá mi Àdùnní Gbogbo yín n mo kí kú ọdún Ẹ ẹ̀ ní tan’ná wo sàréè ọmọ gbogbo wa Mo kí Saheed ọmọ Dòdóńdáwà mi ọmọ Balógun Iwájú lójú gun ń gbé Saheed, o ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn Amin Inú ẹ á dùn lọ́lá Ọlọ́hun Ọba títí dọjọ́ alẹ́ ẹ Saheed Amin Mo k’ó lórí ọ̀dọ́ (olórí ọ̀dọ́) Olórí ọ̀dọ́ méjì ló ń bẹ níbí Ìkan Dèjì Okado Ó represent gbogbo inúmidùn pátápátá Olórí ọ̀dọ́ kejì, òun ni Ríléwá Cooler (Olórí ọ̀dọ́) Cooler, yó dá fún ọ tí ó pọ̀ o (olórí ọ̀dọ́) Èèyàn t’Akin ìlú tọ́jú Meadow (olórí ọ̀dọ́) L’óyìngbò AbdulGaniyu, Barry Shine mo kí ẹ kí ẹ (olórí ọ̀dọ́) Ah! Mo ní mẹ́ta l’Àyìndé lọ́dọ̀ mi o (Mo kí mẹ́ta l’Àyìndé lọ́dọ̀ mi) Mo ní mẹ́ta l’Àyìndé lọ́dọ̀ mi o (Mo kí mẹ́ta l’Àyìndé lọ́dọ̀ mi) Wasiu Àyìndé, Musiliu Àyìndé, Zaria Àyìndé Ọlọ́hun má ṣe l’Àyìndé mẹ́tẹ́ẹ̀ta o (Mo ní mẹ́ta l’Àyìndé lọ́dọ̀ mi) Mo ní mẹ́ta l’Àyìndé lọ́dọ̀ mi o (Mo kí mẹ́ta l’Àyìndé lọ́dọ̀ mi) Wasiu Àyìndé, Musiliu Àyìndé, Zaria Àyìndé Ọlọ́hun má ṣe l’Àyìndé mẹ́tẹ́ẹ̀ta o (Mo ní mẹ́ta l’Àyìndé lọ́dọ̀ mi) Mo kí ẹ màmá soldier o (mama Soldier) Bolanle, ó represent gbogbo United Kingdom London precisely, Bàbá Soldier ọmọ Alátiṣe DNS Gbogbo y8n ni mo kí ẹ kú àdúrótì, ẹ kú ọdún Mo ti kí Bernard láti London Sadiku Murtala ọmọ ọmọ Riri l’Óṣòdì Owó ọkọ Rẹ́nikẹ́, mo kí ẹ Lọ́dún yìí Mà á rí ẹ tẹ̀ míì tọmọtọmọ Aláṣẹ PAGE ní London Sadiku gẹ́gẹ́ bí àdéhùn wa o Mò ń bọ̀ ní PAGE awo ti Milli lágbára Ọlọ́hun Ọba Àmọ̀dún ojú á pé ẹsẹ̀ á pèlé Sadiku èèyàn Jabitha, èèyàn Alhaji Bayshe èèyàn Amuda Yusufu mi Sadiku o kú ọdún Àwa ara wa nímọ̀bà Àwa ara wa nímọ̀bà o Sammy Larry Àwa ló m’ètò ara wa (Àwa ara wa nímọ̀bà) O ṣé! (Àwa ara wa nímọ̀bà o o ) (Ṣèbí àwa ló m’ètò ara wa) Jaguar Àwa ara wa nímọ̀bà Eji, àwa ara wa nímọ̀bà o o Àwa ló m’ètò ara wa (Àwa ara wa nímọ̀bà) Leader (Àwa ara wa nímọ̀bà o o ) (Ṣèbí àwa ló m’ètò ara wa) Prince Saheed ọmọ Adéṣínà Aláṣẹ Unique motors Biliaminu, mo ti rí ọ̀rẹ́ mi o Mo ti ri Mo rí Fúnmiláyọ̀ ọmọ Smith l’Oshodi èkó Òbíńjá ará ìlódò Tapa ọmọ Olúbísí Prince Saheed Adéṣínà aláṣẹ unique Motors Àpamọ́wọ́ owó ńlá ńlá Ẹrù ẹ tó ti tò ò ní dojúrú Prince Bolaji Muhideen Aláṣẹ Bjay Motors Prince Kehinde ọmọ Owólabí Prince Yẹmí Olújìnmí Prince Saheed Adéṣínà Onífádé Lateef mi Gbogbo yín tẹ́ ẹ jẹ́ ọmọ Ọba, ọmọ Ọba ọmọ Ọba Èmi náà mò ń ki yín Àyìndé olórí ọmọ Ọba Ẹlẹlẹ Mesiko ọkọ Mosúnmọ́lá O ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn awo ti Bello mo kí ẹ Bellodos, èèyàn JẸ́JẸ́ motors Àṣàbí Owó ọkọ Fransisca bàbá Korede Fuad ọmọ Ọlọ́tọ̀ máa gbọ́ bí n ṣé ń wí Ọkọ Kore Korede ọmọ baby Lawyer l’Ágàràú area Ṣé ò ń gbọ́ nílé Gbenga Sunday JẸ́JẸ́ Ẹ ẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn gbogbo yín ni mo kí Ah Sultan Ibrahim ọmọ mi Àyìndé mi Wasiu o ò ní ṣánkú mọ́ mi lọ́wọ́ Wàá ma wà nínú ọlá ńlá Agogo kó ró (agogo kó máa ró) #INSTRUMENTAL Agogo kó ró (agogo kó máa ró) Agogo kó ró (agogo kó máa ró) Agogo kó ró (agogo kó máa ró) Ah Bí gbogbo wa bá ń jó (omele kó máa ró) Bí gbogbo wa bá ń jó o(omele kó máa ró) Bí gbogbo wa bá ń jó (omele kó máa ró) Tàbí ṣùgbọ́n ò sí ń bẹ̀ Tiwa làlùjó Fújì o Tàbí ṣùgbọ́n ò sí ń bẹ̀ Tiwa làlùjó Fújì o Ijó ń bẹ ìyẹn ẹ̀wẹ̀dẹ̀ (ijó ń bẹ ìyẹn ẹ̀wẹ̀dẹ̀) #INSTRUMENTAL A gbà p’éjó ń bẹ ìyẹn ẹ̀wẹ̀dẹ̀ (ijó ń bẹ ìyẹn ẹ̀wẹ̀dẹ̀) Serious ṣ’o gbà pé’jó ń bẹ ìyẹn ẹ̀wẹ̀dẹ̀ (ijó ń bẹ ìyẹn ẹ̀wẹ̀dẹ̀) Baálẹ̀ ọkọ ìlú, bo bá ṣe sími ọmọtógbọ́láhàn (ma f’ọgbọ́n ta ẹ́ yọ) Sìró, bo tún ṣe sí mi bó d’ẹlẹ́ẹ̀kejì (ma f’ọgbọ́n ta ẹ́ yọ) Nayam, bo ṣe sí mi bó d’ẹlẹ́ẹ̀kẹ́ta (ma f’ọgbọ́n ta ẹ́ yọ) Istijaba mo ṣe’pé ṣe’pé (Mo ṣe’pé ṣe’pé) Gbénbóyè mo ṣe’pé ṣe’pé (Mo ṣe’pé ṣe’pé) Mo ṣe’pé ṣe’pé (Mo ṣe’pé ṣe’pé) Ṣe pé tí mo wí olúọmọ of Lagos (la fi f’ọgbọ́n ta wọ́n yọ) Ṣe pé tí mo wí olúọmọ of Lagos (la fi f’ọgbọ́n ta wọ́n yọ) Bí wọ́n bínú bínú n ó máa r’àdúgbò mi (Bí wọ́n bínú n ó máa r’àdúgbò mi ò) Bí wọ́n bínú bínú n ó máa w’àdúgbò lọ (Bí wọ́n bínú n ó máa w’àdúgbò lọ o) Níbo làdúgbò mi? (Agarau, Ìsàlẹ̀ èkó, òke pòpó, Ẹ̀pẹ́tẹ̀dó) Níbo làdúgbò mi? (Agarau, Ìsàlẹ̀ èkó, Ìsàlẹ̀ ọ̀fìn, òke pòpó, Ẹ̀pẹ́tẹ̀dó) Dé lafiaji olúọmọ of Lagos (la fi f’ọgbọ́n tawọ́n yọ) Gbogbo àṣà tí mo bá ń dá (Àyìndé mi Gbọ́láhàn ó kẹ̀dẹ̀ ní reason) Gbogbo àṣà tí n bá ń dá (Àyìndé mi Gbọ́láhàn ó kẹ̀dẹ̀ ní reason) Aṣímọlówó Federal àṣà tí mo bá ń dá (Àyìndé mi Gbọ́láhàn ó kẹ̀dẹ̀ ní reason) Àṣà tí mo bá ń dá (Àyìndé mi Gbọ́láhàn ó kẹ̀dẹ̀ ní reason) Goloba ló ń bọ́ o (goloba ló ń bọ́ o) Goloba ló ń bọ́ o (goloba ló ń bọ́ o) Ọ̀rọ̀ tó wà nílẹ̀ yìí (ẹni bà ló mọ̀ o) Kamo state Kamo, mo kí ẹ kí ẹ Congratulations kú oríire Kamo, kú oríire t’ìyàwó ìyàwó aláyọ̀ mi Wà á bí akọ àbíró Kamo, wàá b’ábo àbíró O ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn gbogbo wa ló ń kí ẹ Kamo o Bá ń kí Kamo (bá n kí Kamo) Kamo State, òun pẹ̀lú Esther (bá n kí Kamo) Aya ẹ ló ní n kí ẹ (bá ń kí Kamo) Èmi ò sí nílé nígbà ìyàwó, ni ò jẹ́ kí n wá Wasiu (bá n kí Kamo) Kamo State, yí ó da fún ọ tí ó pọ̀ o (bá n kí Kamo) Gbogbo yín t’ẹ ń ṣe dáadáa Odò tí ń jẹ́ Jelili, Odò! Máa wolẹ̀ máa ràba Amuda mi Yusufu