Olórí d (Live)-文本歌词

Olórí d (Live)-文本歌词

K1 De Ultimate
发行日期:

Fúnmi ọmọ Smith ọmọ Jídé Ẹ bámi kí ọmọ Smith tèmi Àárínọlá Àárínọlá Biliaminu Biliaminu Biliaminu mi (Biliaminu mi) Àárínọlá ló ní n kí ẹ (Biliaminu mi) Àárín ló ní n kí ẹ (Biliaminu mi) Olúpo l’ájàṣẹpo ( Biliaminu mi) Olúpo l’ájàṣẹpo (Biliaminu mi) Olórí ọ̀dọ́ máa wolẹ̀ máa rọra Biliaminu (Biliaminu mi) Funmi gbogbo ìgbà tí ayé bá ń jáyé kiníkan ò ní ṣe ẹ́ nínú àlàáfíà nínú ọlá ńlá O ò ní báwọn gbé ọmọ gbìn bí ọ̀gẹ̀dẹ̀ Iṣu ọmọ tó tú kò ní jó ẹ lẹ́nu Àmín o Olórí ọ̀dọ́ wakado mo kí ẹ Dèjì mi O ṣeun waka Olórí ọ̀dọ́ (olórí ọ̀dọ́) Dèjì Okado yí ọ́ da fún ọ tí ọ́ pọ̀ (olórí ọ̀dọ́) Olórí ọ̀dọ́ yí ó da fún ọ tí ọ́ pọ̀ (olórí ọ̀dọ́) Èèyàn Azeez Jalabia láti Dubai ó ní n máa bá’un kí ẹ ò (olórí ọ̀dọ́) Ọmọ Gbénbóyè ní n kí ẹ o (olórí ọ̀dọ́) Honourable Ifọ̀ Akeem Ọ̀bẹ́kẹ́ ó ní n máa kí ẹ (olórí ọ̀dọ́) Kòṣeégbẹ́ Yinusa ó ní n máa kí ẹ (olórí ọ̀dọ́) Gbénbóyè ọmọ Anọbi Mushin Ó ní kí n kí ẹ (olórí ọ̀dọ́) Ọmọ Ayémojúbà l’áyépé láti Houston ó ní n máa kí ẹ (olórí ọ̀dọ́) Bàbá Khalid ni Canada ọmọ olubisanwá ọmọ àtẹlẹsẹ̀òdúnwọ̀yọ̀wọ̀yọ̀níjẹ̀bú ayépé ó ní n máa kí ẹ (olórí ọ̀dọ́) Dèjì Okado mo gba ara tì ẹ mo fi kí olórí oko bambam Gbogbo inúmìídùn Ibrahim Déńdè Ọ̀gá pátápátá Gbogbo inúùmídùn kó o bá mi kí bo bá délé Ọmọ egúngúngbohùn Dende ko ma bámi ki Ọ̀jẹ̀ ló lòketè baba wa ló l’eégún bó o bá délé bá mi kí gbogbo ilé Hakeem Imra Murphy Ìjẹ̀bú kó o bá mi kí gbogbo wọn Àti Àkànní mi bournvita o Kó o bá mi ki yóbóró yobonsin julanski Kó o bá mi kí gbogbo wọn Himra Al-hakeem olórí ọ̀dọ́ Dèjì, ó yá Dèjì mi (Dèjì mi) Okado olórí ọ̀dọ́ mi (Dèjì mi) Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Dèjì ni Ó wu Ọlọ́hun ló dá Okado lọ́lá (Ó wu Ọlọ́hun ló dá Okado lọ́lá) Ó wu Ọlọ́hun ló dá Dèjì Okado lọ́lá o (Ó wu Ọlọ́hun ló dá Dèjì Okado lọ́lá) Ọ̀tá ẹ yé ṣe dàlé òfo o (Ó wu Ọlọ́hun ló dá Dèjì Okado lọ́lá) Ó wu Ọlọ́hun ló dá Dèjì Okado lọ́lá o (Ó wu Ọlọ́hun ló dá Dèjì Okado lọ́lá) Ọmọ Ọládẹ̀hìndé m’ówó ọpẹ́ wá Honourable Ọládẹ̀hìndé nílùú Ìjẹ̀bú Òde Ó wu Ọlọ́hun ló dá Dèjì Okado lọ́lá (Ó wu Ọlọ́hun ló dá Dèjì Okado lọ́lá) Ọ̀tá ẹ yé ṣe dàlé òfo o (Ó wu Ọlọ́hun ló dá Dèjì Okado lọ́lá) Dèjì Okado yìí o, o ò ní m’òṣì K’óṣì náà má ṣe mọ̀ ẹ́ o Amina Gbogbo ohun tí wọ́n ń báwọn ṣe láyé lo báwọn gbé ilé ayé ṣe o ò ní táwọ́ná Ọ̀tá ẹ á máa rin àrìnkiri, òyìnbó elépo a tún ṣílé epo tuntun Ọjà ẹ tó ti wà lọ́lá Ọlọ́hun Ọba kò ní dojúrú Ó wu Ọlọ́hun ló dá Dèjì Okado lọ́lá (Ó wu Ọlọ́hun ló dá Dèjì Okado lọ́lá) Ọ̀tá ẹ yé ṣe dàlé òfo o (Ó wu Ọlọ́hun ló dá Dèjì Okado lọ́lá) Dèjì Okado o (Dèjì Okado o) Òun l’olórí ọ̀dọ́ wa (Dèjì Okado) Dèjì, èèyàn ni ẹ́, o ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn Orí tó rí ẹ l’ọ́mọdé tó fi gbogbo nǹkan jíǹkí ẹ Ọba má mà gbàá padà o ò ní kú mọ́ wa lọ́wọ́ Nínú ọdún tuntun, èmi ò lóhun méjì tí n máa ṣe Ká ṣà máa dúpẹ́ ká máa ṣ’àdúrà oore Mo gba ara tì ẹ mo kí gbogbo ẹgbẹ́ pátápátá inúmidùn bá ń kí wọn sílé Kó o bá mi tọ́jú Déńdè mi Egúngúngbohùn ó ń gbọ́ Oyii Egúngúngbohùn ó ń gbọ́ nílé Ah! Oyii tí ò yi egúngún Ìlù tó o lù yẹn o fi ṣ’àdúrà ọ̀gá Wàá gbowó ọdún fara ẹ balẹ̀ Okado, mo wá ń bẹ̀ ẹ́ Ọlọ́hun Ọba 2025 Ẹ ẹ̀ ní ṣòwò àìpé gbogbo ohun tẹ́ ẹ bá lówó lé lórí yi ó padà á dowó Ọlọ́hun má wà á ṣe ẹ ni a ẹ̀mí kúkúrú Ìwọ nìkan kọ́ o gbogbo wa ni dórí Déńdè mi ọ̀gá Àti gbogbo inúmidùn àti gbogbo wa pátápátá Àwọn tì ẹ nílùú America wọ́n ní n kí ẹ sílé Èèyàn Pẹ̀lúmi ní Houston Texas Kazeem Ọláńrewájú Ọmọ Ọládẹ̀hìndé honourable nílùú Ìjẹ̀bú Òde Yayi kó o bá mi ki Ẹ bá n ki sílé bá n kí Yayi mi (Yayi mi) Ẹ bá mi kí Yayi mi (Ẹ bá mi kí Yayi mi) Okado olówó yìí, owóo táwọn America Ọmọ àbà ọmọ Ojugbe Ma ṣé fún ẹ, ma ṣé fún ẹ ọmọ Olúbísanwá agẹmọòfíwọ̀yọ̀wọ̀yọ̀ Ọmọ òbìrí l’áyépé Olúbísanwá mi òbìrí o Ọmọ àbà (Ọmọ Ojúgbe) Kúùbọ̀ Ọmọ àbà (ọmọ Ojúgbe) Ọmọ Olúbísanwá o Agẹmọòbíwọ̀yọ̀ ọmọ Olúbísanwá o #INSTRUMENTAL Ọkọ Alhaja Karia ni Canada owó bàbá Khaleed (Ọmọ Olúbísanwá o Agẹmọòbíwọ̀yọ̀ ọmọ Olúbísanwá ó) (Agẹmọòbíwọ̀yọ̀ ọmọ Olúbísanwá ó) Ọmọ àbà (ọmọ Ojúgbe) Ọmọ àbà (ọmọ Ojúgbe) Ọmọ Ayé Mojúbà l’áyépé Ọmọ àbà (ọmọ Ojúgbe) Ọmọ àbà (ọmọ Ojúgbe) Máa gbọ́ bí mo ṣe ń wí Ọmọ Ọládẹ̀hìndé Honourable nílùú Ìjẹ̀bú Òde Ọlọ́hun á gbàá lọ́lá Ọlọ́hun Ọba lọ́lá Ọlọ́hun Ọba Ed direct kó o tọ́jú Yayi bá n ki sílé Ẹ bá mi kí Yáyì mi (Ẹ kí Yayi mi) Ọlámilékan (Ẹ kí Yayi mi) Adéọlá Ọlámilékan (Ẹ kí Yayi mi) Yayi o ti ṣe wàhálà, èèyàn tó s’ègúsí ni yó j’ọbẹ̀ Bó bá wọlá Olúwa (Lékan Yayi mi) Kó o bá mi sọ fun Sọ pé ó ti bá wọn dá tọ́rọ́ o (ó ti bá wọn da tọ́rọ́) Èèyàn ò dẹ̀ ní dá tọ́rọ́ kó má kó sísì Kó mà kó pọ́ùn kan Kó mà kó pọ́ùn mẹ́wàá Ó ti bá wọn dá tọ́rọ́ o (ó ti báwọn dá rọ́rọ́) Honourable Ọládẹ̀hìndé Aṣíwájú ni Shell Sọ fún Yayi ó ti bá wọn dá tọ́rọ́ o (ó ti bá wọn da tọ́rọ́) CEO Ìtẹ̀síwájú Ìjẹ̀bú Foundation Ó ti bá wọn dá tọ́rọ́ o (ó ti báwọn dá rọ́rọ́) Ọlámilékan Yáyì (ó ti bá wọn dá tọ́rọ́) Ah! Ọlámilékan Yáyì (ó ti bá wọn dá tọ́rọ́) Èèyàn ò dẹ̀ ní dá tọ́rọ́ kó má gba pọ́n-ùn Kìí ṣe sísì (ó ti bá wọn dá tọ́rọ́) Kó má gba pọ́n-ùn Gbogbo yín ẹ bá mi tọ́jú Abísọ́lá Ọmọ ti Najimu mo kí ẹ kú ọdún Bìsọ́lá Najimu ṣé ò ń gbọ́ o Àbúrò Fúnmilọ́lá mi sweetie o ṣeun Mo kí ẹ kí ẹ ọmọ ti Najimu mo kí ẹ kú ọdún Ọláńrewájú! Ọláńrewá (Ọláńrewájú) Olúayé Fújì (Ọ̀gá wa o)