Àdíjá Orítókẹ́ Ó jíṣẹ́ ẹ fún mi Bọ̀sun mi Ọ̀rẹ́dọlá Gbogbo yín ẹ kú àdúrótì Afọlashadé Bọ̀sún mi Ọ̀rẹ́dọlá Làbákẹ́ baby, Làbákẹ́ baby Adéọlá Bọ̀sún Bọ̀sún Ọ̀rẹ́dọlá Àdíjá Orítókẹ́ ó mà jíṣẹ́ ẹ fún mi o Bọ̀sún Èkó mi máa wolẹ̀, olorì Èkó Èní là ń ṣe ọjọ́ọ̀bí bàbá wa Àkànní Rasaki oníléajé Eleganza Ọkọ́ya bàbá mi Àkànní Family Ọkọ́ya arábámbí Àkànní onílé ajé ọ̀rẹ́ ọmọ Ọba Samuel Adédoyin Bàbá mi ní làgbámú Àti Samad àti Aliko àwọn méjèèjì wọ́n ní kí n ki yín Pa mi Eleganza Ọkọ́ya Abdulsamad Rabiu àti Séríkí elépo Séríkí Mesugar Aliko Dangote Ali náà ní n kí ẹ Hadiza baby, ijó dijó family Àkànní adé, Èní lẹ̀ ń ṣe ọjọ́ọ̀bí Baami oníléajé Àkànní Rasaki mi Mo recognise presence Ọ̀gbẹ́ni Ọjà Akilẹ̀ Ìjẹ̀bú Máa wolẹ̀ máa ràba baàmi Chief Sanni mi Kuku mi Sanni Kuku m kí ẹ Chief Sanni Kuku mo kí ẹ kí ẹ nílùú Ìjẹ̀bú Òde Ẹbí Eleganza Ọkọ́ya Gbogbo family pátápátá, family Ọkọ́ya Túndé Taofeeki gbogbo family Ọkọ́ya Bàsírá láti kékeré (láti kékeré) Àti èmi ẹ àti Mojísọ́lá la ti jọ kí ṣọ̀rẹ́ bọ̀ (láti kékeré) Àti Taofeek àti Tunde Ọkọ́ya (láti Kékeré) Àti Bíọ́lá Ọkọ́ya (láti kékeré) Tèmítáyọ̀ mo kí ẹ kí ẹ aya Moyọ̀ Bàbá onífẹ́lẹ̀lẹ̀ Alhaji Tajudeen mi Ọkọ Rashedatu mo kí ẹ kí ẹ Alhaja Rasheeda A kú oríire ti bàbá wa Alhaja Rashedatu Rasheeda Ọkọ́ya mo kí i yín Ọ̀rẹ́ Alhaja Mosúnmọ́lá mother Fathia alálùbáríkà o Alhaji Rashedatu ìyá Ọba, mo kí ẹ kí ẹ Rasheeda Aya Tajudeen Ọkọ́ya Rasheeda Eleganza mi (Eleganza mi) Bàsírá, Basira mo kí ẹ kí ẹ (ọmọ Eleganza mi) Basira mo kí ẹ kí ẹ (ọmọ Eleganza mi) (Arabic Recitation) Ọlọ́hun ránsẹ́ pe ànọ́bì ní ọ̀sán kan òru kan Bó ti ń gun sánmọ̀ pẹ̀lú ẹṣin ògo Bẹ́ẹ̀ ló ń pe Olúwa Ọba Alárànṣe Tó ń sọ pé Lahillah Ọba Olúwa mi Ọ̀nà wo ni n ó gbà ti n fi dé ọ̀dọ̀ ẹ Ọba Ọlọ́hun bá sì dáhùn (Ìwọ ànọ́bì mi) Máa pé Semia Basira Walimo Wahaya (Semia Basira Walimo Wahaya) Okay, ẹ má ba wí ẹ má ba jà (Basira k’ẹ́nìkan má sọ̀rọ̀ ẹ lẹ́yìn Basira) Ẹ má ba wí ẹ má ba jà o (Basira k’ẹ́nìkan má sọ̀rọ̀ ẹ lẹ́yìn Basira) Bí n ṣé rántí Basira mi ò lè gbàgbé Mojí Ọkọ́ya Bàsírá Mojí aya Tẹ́júọshọ́ mi (Basira) Mi ò le gbàgbé Bíọ́lá Ọkọ́ya Basira Túndé Ọkọ́ya (Basira) Taofeek Ọkọ́ya (Basira) Bọ́lájí Ọkọ́ya (Basira) Bím̀bọ́ Ọkọ́ya (Basira) Idirisu Ọkọ́ya (Basira) Mi ò le gbàgbé Tòkunbọ̀ (Basira) Láyí Ọkọ́ya (Basira) Lẹnì Ọkọ́ya pẹ̀lú Títí pẹ̀lú Tóyìn Ọkọ́ya (Basira) Mi ò le gbàgbé Hadiza (Basira) Hadiza Akala (Basira) Bàsírá mo kí ẹ (Basira) Ó yá Basiratu o (ah ah Basiratu o) Táuọ̀ Ọkọ́ya, jubril Ọkọ́ya, Fareedah Ọkọ́ya, Wálé Ọkọ́ya, Bíọ́lá, Ya wahabi Ọlámidé, Oyinlọlá àti Ṣùbòmí Àwọn ọmọ Eleganza Ọkọ́ya Onílé ajé (onílé ajé) Onílé ajé (onílé ajé) Mi ò le gbàgbé Bùnmi pẹ̀lú Táyọ̀ Onílé ajé (onílé ajé) Bàsírá a ti jọ mi ṣeré bọ̀ (láti kékeré) A ti jọ mi ṣeré bọ̀ (láti kékeré) Ọmọ Ọba Ṣọlá olorì ṣe o ò gbàgbé? A ti jọ mi ṣeré bọ̀ láti kékeré Basiratu mi (Basiratu mi) O ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn (Basiratu mi) O ò ní dọlárẹ̀yìn (Basiratu mi) Kó o bá mi kí Tẹ́júọshọ́ (Mojí Tẹ́júọshọ́) Kí Mojí Tẹ́júọshọ́ (Mojí Tẹ́júọshọ́) Àti Bíọ́lá Ọkọ́ya (Mojí Tẹ́júọshọ́). Olorì ọmọ bàbá làgbámú Ó ń náwó Basiratu Mojí Tẹ́júọshọ́ (Mojí Tẹ́júọshọ́) Tunde Tunde Tunde Tunde Tunde Tunde Tunde Tunde Tunde Tunde Tunde Tunde Ọmọ Eleganza Ọkọ́ya ọmọ Àkànní adé Kiní kan ò mà ní ṣe ẹ o Túndé (Ọmọ Eleganza Ọkọ́ya ọmọ Àkànní Adé)