Planning Committee (Live)-文本歌词

Planning Committee (Live)-文本歌词

K1 De Ultimate
发行日期:

Ijó dijó organising committee, planning committee chairman

Bíọ́dún Ishola ọmọ t’Èjígbádéró

President Alimosho pillars

Comrade Alawaye..

Chairman planning committee 2016 & 17

Honourable Francis Adebisi coordinator

Alimosho Day, APC Youth Leader

Engineer Abíọ́dún ọmọ t’Àríọrí

Aríọrí mi ọ̀gá ńlá

Budgeting, Alimosho Day, honourable Ayọ̀dẹ̀jì Kọ́láwọlé

Chairman organizing committee

Honorable Mrs Akíndélé Ọpẹ́yẹmí Chairman Finance Committee

Alhaja Ìyábọ̀dé Akínlàdé

Akínlàdé Leilah, Chairman Social Welfare Committee

Jamiu Sádéyan Chairman Football committee

Alhaji Ahmed Yusuf chairman media committee

Prince Okonkwo Christopher, chairman duty committee

Ọmọ́tọ́lání Adédayọ̀, Obama Tọ́lání ọmọ t’Adédayọ̀ Tọ́lání

Security committee Adédayọ̀ Tọ́lání

(Instrumental)

Tọ́lání Adédáyọ̀, chairman security committee

Honorable Suleiman ọmọ Gbàdàmọ́sí

General Secretary, gbogbo yín ẹ kú ọdún Alimosho 2017

Ishola Abíọ́dún ọmọ t’Èjígbádéró

President Alimosho Pillars yìí o ṣé

Ọkọ Láyínká Silifata ayaba

Bàbá Tèmítọ́pẹ́, Bàbá Títílọpẹ́, Bàbá Faruk mi, Bàbá Fawaz mi

Aláṣẹ Jimsol Heritage properties Limited

Ẹ̀gbọ́n Tajudeen mi ọmọ Èjígbádéro

Awo Tunde ọmọ Bọ̀rọ̀kìní Boro

Awo Lukman ọmọ Fowótadé, awo t’Akanni Razak mi ọmọ ti Ọláńrewájú

Lord Mayor Royal Pioneer, awo Oris mi òyìnbó

Member Royal Pioneer Club Bíọ́dún Bíọ́dún, Abbey ọmọ Èjígbádéro

Ọdọọdún là ń rí orógbó, Bíọ́dún

Ọdọọdún là ń rí Awusa

Ọdọọdún là ń r’ọ́mọ obì lórí àtẹ o

Wàá máa wà pẹ̀lú owó lọ́wọ́, lálàáfíà ara Bíọ́dún mi ọmọ t’Èjígbádéró

Kí là ń fowó ṣe bí a bá lówó lọ́wọ́, àdẹ̀ fi ká fowó ra iyì náà ni

Bíọ́dún mi Abbey mi ọmọ t’Èjígbádéró, Abíọ́dún ń fi ọlá ra iyì tó pọ̀ rẹpẹtẹ

Aìí láhùn níyì, gbogbo náwó náwó

Náwó náwó ń fowó rayì náà ni

Ẹ̀bẹ̀ kan mò ń bẹ ọlọ́hun Ọba Àyìndé adé

Ọba má pa kádàrá mi dà sí aburú ọmọ ń fowó rayì náà ni o

Ẹ̀bẹ̀ tí mò ń bẹ Ọlọ́hun Ọba lórí ẹ Bíọ́dún o

Ọba má pa kádàrá ẹ dà sí aburú

Èjígbádéro ń fọlá rayì náà ni Abbey ọmọ t’Èjígbádéró

Ó ní kí n bá òun kí gbogbo Royal pioneer

Royal pioneer club, Abbey NÍ kí n dúpẹ́ lọ́wọ́ gbogbo ẹgbẹ́ láti orí Àkànní mi Rasaki, ó ní n dúpẹ́ dúpẹ́

Tì ẹ á dára o Èjígbádéro Abbey o

(Tì ẹ á dára Èjígbádéro Abbey o)

Ọ̀rọ̀ tì ẹ á dára Èjígbádéro Abbey

Ọmọ ni Bíọ́dún, Bíọ́dún mi Abbey

Olórí ẹgbẹ́ Alimosho Pillars

Ọkọ Ọláyínká tí ń jẹ́ Silifatu

Ọkọ Silifatu mi Ọláyínká mi ọmọ Èjígbádéró