wn Alfa (Live)-文本歌词

wn Alfa (Live)-文本歌词

K1 De Ultimate
发行日期:

Excellent Alfa wa

Excellent máa wo’lẹ̀ má ràba

Abdullah mi, ọkọ Alhaja Sekinatu yìí o ṣe, ọkọ Amina

Awo Abìọ́lá Salam mi

Àbúrò Surajudeen mi káre arisukuna

Àbúrò Surajudeeni mi Suraju Arisukuna

Suraju Excellent, ọ̀rẹ́ Ọlọ́run

Excellent, ọ̀rẹ́ ànọ́bì Muhammad oníṣẹ́ ńlá

Ìlú Àbújá lọmọ mà wà

Alhaji Excellent! Etí inú

Awo General Babangida

Alfa ni Allihulamohu ni

(Arabic titles)

Ohùn yẹn gangan t’ànọ́bì Muhammad oníṣẹ́ ńlá

(Arabic titles)

Ìyẹn ni t’ànọ́bì oníṣẹ́ ńlá, ọlá bàbá Fatimo

Àṣírí Ọlọ́run ẹ ò le rí

(Arabic)

Alfa tiwa, tó ń kéwú lẹ́gbẹ̀ẹ́ ilé yín

Tó bá máa ṣakọ..

(Arabic recitation)

Kéwú lápò Alfa tìẹ

Okay àwọn Alfa tèmi…

Abdullahi mi Excellent

.. ọ̀rẹ́ Ọlọ́hun .. ọ̀rẹ́ Ọlọ́hun

Ọ̀rẹ́ ànọ́bì Muhammad ọlá bàbá Fatimo

(Arabic recitation)

Awo Abíọ́lá Salam awo Iburaimo Babangida

(Arabic recitation)

Àwọn Alfa tì ẹ tí wọ́n ń ṣ’agídí p’áwọn kọ́ kéú

Bí ẹ bá bi wọ́n kíni wọ́n ń wí

(Arabic recitation)

Wọ́n máa ká lòlò tí wọ́n bá ń kọ́ kéú

Àwọn Alfa tiwa, ẹ má sáré owó

Mo mọ orúkọ Ọlọhun Ọba òun ni mo ṣe ń yan o

(Mo mọ orú’, mo m’orúkọ Ọlọ́hun Ọba o)

(Òhun ṣá ni mo ṣe ń yọ̀ Arábámbí)

Mo mọ orúkọ Ọlọhun Ọba òun ni mo ṣe ń yan o

(Mo mọ orú’, mo m’orúkọ Ọlọ́hun Ọba o)

(Òhun ṣá ni mo ṣe ń yọ̀ Arábámbí)

(Arabic recitation)

Àdúrà ó ti gbà ameena

(Arabic recitation)

Àdúà mi, Àdúà yó máa gbà lójoojúmọ

Alfa mi, àdúà yín ma gbà lójoojúmọ́

Lọ́lá àṣírí Ọlọ́hun Ọba tí ò ṣe é tú

(arabic recitation)

Mi ò sọ̀kọ̀, Arábámbí mi Àyìndé ẹ gbọ́mi dáadáa

(Arabic recitation)

Abdullahi, wọ́n ó máa tẹ̀lé ẹ ni o

(Wọ́n ó máa tẹ̀lé ẹ ni)

Wọ́n ó máa tẹ̀lẹ́ ẹ ní o

(Wọ́n ó máa tẹ̀lé ẹ ni)

Ẹ̀yìn ẹ̀yìn lọmọ kéú ma ń tọ Alfa

(Wọn ó máa tẹ̀lé ẹ ni)

Ẹ̀yìn ẹ̀yìn lọmọ kéú ma ń tọ Alfa

(Wọ́n o máa tẹ̀lé ẹ ni)

Ìwọ ti b’Ọlọ́hun dúró Abudullahi

(Wọ́n ó máa tẹ̀lé ẹ ni)