Aségun1-文本歌词

Aségun1-文本歌词

Sola Agunbiade
发行日期:

Jeeesuu, Kristi oooo,

So mi d’eni asegun mo be ooo x3

1.

Lati inu ibu wa, ni mo ke pe Oluwa,

Lati inu ogbun ese, mo ke p’Olugbala mi,

Ogun aye mi le koko, isoro aye mi o legbe,

Abuku aye mi n ti mi loju, egan aye mi p’apoju.

Iwo ni mo gbagbo oo, mase je k’oju o ti mi ooo

Olorun mi ja fun mi mo be ooo.

Chorus

Iwo ni mo gbagbo oo, mase je k’oju o ti mi ooo

Eleda mi ja fun mi mo be ooo. X2

2.

Oruko Oluwa, ile iso agbara ni,

Emi ti sa wo ‘be, ota le mi won o ba mi,

Won tun le mi titi, won le mi d’odo Kristi,

Olugbala bi mi pe, awon olufisun re da!

Mo ni mi o ri won mo,

O ni n sa kuro fu ese, ki n lo ni idalare

L’aye mi ba yi pada, mo ba d’eni aye n ye,

Olorun mi gba akoso mo be oo.

Chorus

Iwo ni mo dimu oo, mase je k’oju o ti mi ooo

Eleda mi gba akoso mo be ooo. X2

3.

Iseda aye mi san, sugbon omi ise koro,

Ile idile saa, mo n sise bi erin, ko sohun amu yagan,

Iyo inu awo koto, lo sawotan Jeriko o,

Ko si iku mo, ko si arun, omi dun aye dara,

Eyi ma ni eri mi, jowo mase je ese mi ye,

Mu mi dele ologo mo be oo.

Chorus

Olorun mi gba mi oo, ota n fi mi s’eleya

Aye mi ma d’owo re o gba ooo. X2